Wizka – Jerimoyah Lyrics

, Thrill out with a smashing brand new mind blowing single titled “Jerimoyah”. Dive into the word catchy .

Enjoy the Lyrics of “Jerimoyah” by Wizka

DOWNLOAD NOW!

Listen below:-

DOWNLOAD MP3 [2.75 MB]

Wizka – Jerimoyah Lyrics

[Intro]
Wur-uh-uh-uh-uh-uh-uh-uh
EE-Ee-ee-ee-ee
(???)
Wizka makun sko, oh-oh
Yeah-eh-eh-eh

DOWNLOAD MP3 SONG 

Jerimoyah l’é
Rimoyah l’èmèjè
(Train Wavy TK, mix it, baby)
Oh, Yeah-ay-ay-ay
Jerimoyah l’é, Jerimoyah l’èmèjè
Jerimoyah l’émèjè, aw-l’émèjè

[Chorus]
Jerimoyah l’émèjè
Ọbá t’òn gb’èdè k’èdè
Ọbá tòh dári sànmón mèjè o
Ọbá tiò ma l’áfiwè

É jé á sòh itàn jànmó mèji
L’óbá ló s’ódó wòli
K’òlè d’ólá, k’òlè nìyi
Wòli s’óró f’ákókó

Wi pè òwò nbó wá fún
Sugbón láálá póju
F’òmó édá Adam
Wòli té siwáju ló

L’òbá s’óró fún ikèji
Wì pè á r’òwò òjijì
L’òbá kò ájè mèji
L’ówó awón jànmó mèji

[Post-Chorus]
Wì pè “é wì nté fé si
L’òwuró f’ójó mèjè
Sugbón ranti ènìkèji
Ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi

T’òbá d’èni, ò lè d’ólá, kò d’òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d’árá

[Verse 1]
Òju áyè
Ò bá gbó nti time sóh
Wá mó pè kò s’áláyè
Ò nì ìbì t’èrè pór sunmó

Ni ikèji át’ákókó
Wòli má l’òn f’èdè fọh
Wì pè “kòsi anybody
Tá nkán t’Òluwá wì

Ákókó l’ólá pó ju
Ò s’óró s’ájè pó ju
Ikèjí d’éri ípónju
Ò p’òshé ju ájè sọn

Ilahi, Óbá yì
Má shèè wò mi
Ábiámọ t’òlójá yì
Mò d’èrò t’òri gáhin, Ilahi

[Refrain]
Ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi (ye-ye)
T’òbá d’èni, ò lè d’ólá, kò d’òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi
T’òbá d’èni, ò lè d’ólá, kò d’òdì fún ikèji

Ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi
Ò lè d’ólá
(Train Wavy TK, mix it, baby)
Kò d’òdì fún ikèji

End Of Jerimoyah Lyrics